OYEOLOHUN TV
Gbígbé àṣà àti ìṣe pẹ̀lú èdè Yorùbá lárugẹ ló jẹ wá lógún.
Ẹ lè kàn sí wa lórí:
*Instagram: oyeolohun_tv
*Tiktok: OYEOLOHUN_TV
*Facebook: Oyeolohun88
Gmail: [email protected]
Ẹ seun tí ẹ̀ ńtẹ́tí gbọ́ wa, ẹ le pè wá sí ẹ̀rọ ìbára ẹni sọ̀rọ̀ yìí 08069316812. Bí ẹ bá ní ohun láti bá wa sọ. Ire ni tiwa tẹ̀yin lọ́jọ́ gbogbo. Ooodabọọọ. 🙏
OGBOJU ODE // MO YIN IBON SI ABAMI ALEGBA, EBORA(DEMON) KOMI LOOGUN MEJI, ALEGBA SORO JADE BI ENIYAN
OGBOJU ODE // EBORA (DEMON) EMI AIRI (SPIRIT) LOOGUN TI ENIYAN BASE TO NJE, ISE OWO NISE ISEGUN FUN.
OGBOJU ODE // IWIN (SPIRIT) EBORA (DEMON) YI WA KA, WON FE BAMI JA, MOBA ORO IGI OPE NIBI TO JOKO SI
OGBOJU ODE // EBORA (DEMON) IWIN (SPIRITI) TORO AASA LOWO MI, O KO MI LOOGUN, O BUNMI NI IYAN & OBE.
OGBOJU ODE // A MA NPADE IWIN (MALEVOLENT) EBORA (DEMON) NINU IGBO ODE TOMA NKOWA LOOGUN, EMI AIRI..
OGBOJU ODE // EMI (SPIRIT) KAN NI IFA JE NITORI ONA TI IFA NGBA BA BABALAWO SORO PO, IFA KIISE EBORA
OGBOJU ODE // MYSTERIOUS HUNTER, MO YIN IBON SI EKULU ABAMI (SPIRIT) O SARE WONU OKITI, IWIN (DEMON)
OGBOJU ODE // EBORA (DEMON), EMI AIRI (SPIRIT) ALUJONNU (GENUS) ATI EGBERE (MALEVOLENT) PELU ORO IG.
OGBOJU ODE // MO PADE IWIN (GENUS) MORI TO TAN INA SI MI LOOKAN, MO NTO EBORA (A SPIRIT) NAA LO...
OGBOJU ODE // IJI (STORM) YIRA PADA SI ABAMI (SPIRIT) EDA, O TORO AASA LOWO BABA MI, O KO WA LOOGUN.
OGBOJU ODE // KEKERE NI MOWA TI AWON EMI AIRI (SPIRIT) TIMA NWA BAMI SERE, MO MA NGBO OHUN (VOICE).
OGBOJU ABOLE || IRINJU AWON AGBALAGBA NI MI// ENITI A BA NIKI WON TU SILE, YOO DI TITU SILE LASE...
ODU IFA OYEKU MEJI; TI A TUN NPE NI OYEKU LOTUN, OYEKU LOSI.
ALUJONNU TABI EBORA RI RAN NISE KO SORO BEENI KOLE SUGBON ATUBOTAN RE KO DA....
OGBOJU OLOOGUN: ORI AFEFE NI MOTI MA NFUN ENIYAN LOOGUN LO, KIISE DANDAN NIKI A FI OOGUN RANSE SIYAN
IYA MI ABENI EDE, YIRAPADA SI OBINRIN AJOJI WA BAMI NI IDIKO, KI IJAMBA OKO LE FORI MI...
EBORA, IWIN, ALUJONNU, ORO, AFEFE NI GBOGBO WON NBA SISE, KOSI IBITI WON KO LEDE LAARIN ISEJU AAYA..
Iwin, Alujonnu, Nbe Ninu Eranko, Ojo Ti Eranko Igala Lohun Yoo Pami, Ojo Male Gbagbe Ni...
ĘBORA YATO SI ALUJONNU, EEWO GBODU LEEWO AYERAYE NITORI EEWO IFA DIDA YATO SI EEWO GBODU...
GBOGBO ENIYAN LO YE KI O TE IFA, KI A LE MO EEWO TI O NI JEKI A TETE DEBI OGO WA...
OMO ODE MI YIN IBON PA ERANKO AFIRIMOJO, IYAWO RE SI KU NILE KI O TO SE ETUTU RE...
OGBONTAGI ODE || Eemetadinlogun Ni Mo Wa Saye Ki nto duro, Agbara Adayeba lagbara ti mo nlo...
Alujonnu Loni Gbogbo Oogun ti a nse patapata, Ebora le yira pada si ohun kohun toba wu...
IRIRI ODE // Mo Pade Alujonnu Mo mi ori si, Mo tun ba oku to fi aso funfun bora loju ona...
IRIRI ODE || Alujonnu tele mi lati inu igbe wasi ibudo, Mo yin ibon si ajanaku, mo jasi ilu aimo..
OGBOJU ODE || Alujonnu Eniyan ni baba mi, O ku to oore ogun ki o to fi aye sile, Alagbara ni...
OGBOJU ODE || Aye nsare ju bi gbogbo wa ti lero lo, bi moba toju Eniyan tan ni mo to ma ngba nnkan..
OGBOJU ODE || Alujonnu ni kii jeki ode ri omo eranko to yin ibon si gbe lopo igba ninu igbe...
OGBOJU ODE || Awon Oogun Orisi Meta Kan Nbe Ti Eni Toba Pe Ara Re Ni Ogbontagi Ode Gbodo Ni Lowo...