ODE ILU IBADAN TV
Subscribe to ode ilu ibadan tv
IGALA NI MO YINBON SI, OYIN TA MI TI NKO RIRAN MO, DIE LO'KU KI NKU.
AWON BANDIT DAWA LONA NINU IGBO.
ODE KAN YINBON LU ARAA'RE LOKO ODE.
OJO META LAWA OGOJI FI SE ODE NI AKATANPA , AA PA EKU, ASAN LA N JEUN.
EFON TA YINBON SI PADA SE BABA ODE WA LESE , KO S'ODE MO DI ONI.
EJO SEBE WO INU SOKOTO MI LO, MO TI SUN LO LORI EGUN, OJO YEN BURU JU.
IGALA TI MO PA NI IGBOGOGO, IWO EYOKAN LO NI, O SI SO'PA.
ODUOYA MEJO NI MO PA LOOTO, ERAN EWURE META NI MO FI SETUTU
NI ILU RANGANMU, NITOSI IFE ODAN , IWIN KAN WA NIBE , AMIDA LORUKO RE.
LOJO TAWON KAN BU IYA TO BIMI, EPE NI MO FI BA'WON JA.
OJO META NI MO LO LODO IWIN OKUTA'DO, TORI MO PA ERAN RE.
Die L'oku: Eran Igala Ti Mo Pa Fe Fi Iwo Bo Mi Ni'kun. Oyingbo Ode Lanlate.
EGBIN META MOSIA KAN NI MO YINBON SI, TI MI O PA OKANKAN, ASEE, EJO LOWO NINU.
MO FUN IWIN NI IFINMU, OHUN NAA JUWE ILE ERAN FUNMI.
IKOODE MERIN LAA BA NINU IGALA TAA PA LOKO ODE :::::::
MO YINBON PA ETU NIWAJU , ETU KU, ENI TO WA LEHIN MI NI IBON BA OHUN.
EPE, AFOSE, OLUGBOHUN, TI MO KO'JO, MO N SIN WON NI.
IYA AGBA KAN LABULE WA SO PE , ERAN OYA TI MO PA ERAN AWON NI.
MO YINBON PA EHORO, IYAWO MI SI LOYUN, APA IBON YEN SI WA LARA OMO YEN DI ONI.
IRIRI ODE ERIWONWO NIGBO BURY, PELU TOKOTAYA TI MO PADE. Part 3
MO MA N PADE AWON IWIN, LATARI AWON OOGUN TI MO NLO. Agbagbe part 2
ODE AGBAGBE LORI OKU , NI IBUDO IJONGBON . PART 1.
IRIRI ODE ERIWONWO NIGBO AGINJU ATI IGBO OBA. Part 2
ODE ERIWONWO NINU IGBO RESERVE PART ONE
ERAN IGBE LO WU ODE ODO KO FI JE SAARI, SE YOO PAGALA NINU OMI NI.
MO JE ODE ADEDO, MO TUN N DE IGBO. ODE ARIBIKOFA
OOGUN NBE, SUGBON OOGUN FEE SUNKO LOJO TI MO YINBON MO AKITI.
IYAMODE IWERE OKE , PART 2. ode obinrin.
MO N DARI OKO ODE BO, MI O MO ENI TO SA MI NI ADA, NI AARIN ORU.
BABA IYABO PA IGALA TO WO ABULE WA, ILE IWE LO PE'RAN SI.