A.L.F YORUBA TV
This channel was created for news updates📢, documentaries💽, histories in the world🗞️ and to educate it audience📚. Kindly help this channel by clicking the subscribe button, by sharing, by clicking the like icon and comment to promote it more. Thanks for your unwavering support. A.L.F TEAM LOVE YOU ALL❤️
ÀWỌN BOKO HARAM NI O! GBAJÚMỌ̀ OLÓṢÈLÚ TÚ ÀṢÍRÍ ÌJỌBA PÉ ÀWỌN BOKO HARAM NÁ Ń KÓ SÍNÚ IṢẸ́ SỌ́JÀ O
ÀṢÍRÍ TÚ O! ÀWỌN ỌLỌ́PÀÁ TI KÓ ÀWỌN FÚLÀNÍ JÁDE NÍNÚ IGBÓ TÁN SÁPAMỌ́ SÍ NÍ ÌPÍNLẸ̀ ÒGÙN O
AKỌNI LỌ O! ỌLỌ́DẸ YÌÍ FÀYÀ GBỌTA ÌBỌN LÁSÌKÒ TÁWỌN AGBÉBỌN FẸ́ JÍ ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ GBÉ NÍLÉ ÌWÉ
OLÓRÍ KÚ IKÚ ORÓ O! ÀWỌN ỌMỌ OGUN YABO ÀWỌN AGBÉBỌN LÓJÚ IGBÓ, WỌ́N PA OLÓRÍ BANDITS NÍPAKÚPA
OGUN OJOOJÚMỌ́! ÀWỌN AGBÉBỌN TÚN YAWỌ ÌLÚ, WỌ́N JÍ Ọ̀PỌ̀ ÈNÌYÀN GBÉ PẸ̀LÚ ALÁBOYÚN LỌ́SÀN-ÁN GANGAN
A DÚPẸ́ O! ÀWỌN ỌMỌ OGUN YAWỌ IGBÓ, WỌ́N HÚ OLÓRÍ ÀWỌN BANDITS JÁDE NÍNÚ IGBÓ BURÚKÚ TÁN SÁ SÍ
A ṢE TÁN LÁTI JÍ TINUBU GBÉ! ÀWỌN AGBÉBỌN TI KÉDE Ọ̀NÀ TÍ WỌ́N FẸ́ GBÀ JÍ TINUBU GBÉ O
ÀWỌN ỌDẸ BÍNÚ TÁN O! ÀWỌN ỌDẸ YABO ÀWỌN BANDITS, WỌ́N PA MẸ́FÀ NÍNÚ WỌN,WỌ́N GBA ÌBỌN AK-47 MÉJE
A DÚPẸ́ O! ÀWỌN ỌLỌ́PÀÁ YAWỌ INÚ IGBÓ ÀWỌN AGBÉBỌN, WỌ́N GBA ÀWỌN ỌMỌ TÁN JÍ GBÉ SÍLẸ̀ O
Ẹ SÁ KÚRÒ NÍLÉ ÌWÉ O! ÀWỌN AGBÉBỌN TI Ń BỌ̀ WÁ SÁWỌN ILÉ ÌWÉ ÀTI ILÉ ÌJỌSÌN NÍ ÌPÍNLẸ̀ MÌÍRÀN O
JAMIU SÌṢE O! JAMIU FẸ́ SÒGÙN OWÓ LÀWỌN Ọ̀RẸ́ RẸ̀ BÁ PA Á SÍNÚ IGBÓ NÍBÀDÀN FÚN TI ARA WỌN
Ẹ WO BÍ ÌBỌN ṢE Ń DÚN LÁKỌLÁKỌ́! ÀWỌN BANDITS YAWỌ SỌ́Ọ̀ṢÌ WỌ́N ṢEKÚ PA ÀWỌN ÈNÌYÀN NÍPAKÚPA
Ọ̀FỌ̀ ŃLÁ LÈYÍ! ÀWỌN AGBÉSÙNMỌ̀MÍ PA Ọ̀GÁ ÀGBÀ SỌ́JÀ NÍPAKÚPA/ÀWỌN Ọ̀DỌ́ ÌLÚ TÚN GÚN Ọ̀GÁ MÌÍRÀN PA
WÀHÁLÀ DÉ O! ÀWỌN AGBÉBỌN TI YAWỌ INÚ ÌLÚ YÌÍ PẸ̀LÚ ÌBỌN ŃLÁŃLÁ LỌ́WỌ́ WỌN, ÌBẸ̀RÙ WỌ̀LÚ
WỌ́N TI YAWỌ ILÉ ÌWÉ O! Ó DÓJÚ Ẹ̀ PO, ÀWỌN AGBÉBỌN JÍ ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ GBÉ, WỌ́N TÚN PA Ọ̀GÁ ILÉ Ẹ̀KỌ́
Ẹ WO ÌBỌN ŃLÁŃLÁ! ÀJỌ DSS YABO IBI TÁN TI Ń ṢE ÌBỌN FÁWỌN BANDITS, ỌWỌ́ TẸ OLÓRÍ TÓ Ń ṢE ÌBỌN
ÒKÚ WỌN RÈ É NÍLẸ̀! ÀWỌN ỌMỌ OGUN JU ÀDÓ IKÚ SÓRÍ ÀWỌN AGBÉBỌN, WỌ́N SUN WỌ́N JÓNÁ RÁÚRÁÚ
IKÚ ORÓ TI PA OLÓRÍ O! ÀWỌN ỌLỌ́PÀÁ ÀTI ỌLỌ́DẸ YABO ÀWỌN AJÍNIGBÉ, WỌ́N ṢEKÚ PA OLÓRÍ WỌN NÍPAKÚPA
GBANGBA DẸKÙN O! ỌWỌ́ TẸ ÀLÙFÁÀ ALÁBỌ̀DÈ TÓ Ń ṢIṢẸ́ PẸ̀LÚ ÀWỌN AGBÉBỌN NÍNÚ IGBÓ. ÀṢÍRÍ ŃLÁ
Ó DÓJÚ Ẹ̀ PO! Ẹ SANWÓ ORÍ YÍN FÚN WA TÀBÍ KÁ KÓGUN JA GBOGBO YÍN, ÀWỌN BANDITS FOHÙN RÁNSẸ́ O
ÌSẸ́GUN ŃLÁ LÈYÍ O! ỌWỌ́ TẸ Ọ̀GỌ̀RỌ̀ AJÍNIGBÉ TUNTUN MÌÍRÀN PẸ̀LÚ ÌBỌN ŃLÁŃLÁ LỌ́WỌ́ WỌN
Ó PARÍ FÚN OLÓRÍ ÀWỌN BANDITS O! ÀWỌN ỌMỌ OGUN YABO IBÙGBÉ ÀWỌN BANDITS, WỌ́N ṢEKÚ PA OLÓRÍ WỌN
ÀWỌN ỌDẸ ṢE BẸBẸ O! ỌWỌ́ TẸ ÀWỌN FÚLÀNÍ AJÍNIGBÉ MÉJÌ NÍ ÌPÍNLẸ̀ Ọ̀YỌ́ PẸ̀LÚ OWÓ TABUA LỌ́WỌ́ WỌN
FÚLÀNÍ ṢÌṢE O! ÀWỌN FÚLÀNÍ DA MÀLÚÙ WỌ ILẸ̀ ÍGBÒ LÀWỌN IPOB BÁ YÌNBỌN PA WỌ́N NÍPAKÚPA
EWÉ SUNKO O! LẸ́YÌN TÍ AGBÉBỌN YÌÍ GBÉ OÒGÙN WỌ̀ TÁN, Ó KỌJÚ ÌJÀ SÁWỌN ỌMỌ OGUN, LÓ BÁ KÚ IKÚ ORÓ
WOROSÍWORO LÈYÍ O! ÀWỌN AGBÉBỌN YAWỌ ÌLÚ, ÀWỌN ỌLỌ́DẸ DÁNÁ YÁ WỌN, WỌ́N SÁ WỌGBỌ́ LỌ O
ÈYÍ DÁRA O! ÀWỌN AGBÉBỌN PÀDÉ ARA WỌN LÓRÍ OMI ŃLÁ, WỌ́N PA ARA WỌN NÍPAKÚPA NÍTORÍ IPÒ AGBÁRA
ÌṢẸ́GUN ŃLÁ LÈYÍ O! ÀWỌN ỌMỌ OGUN YAWỌ IGBÓ ÀWỌN AGBÉBỌN, WỌ́N TÚ Ọ̀PỌ̀LỌPỌ̀ ÈNÌYÀN SÍLẸ̀ NÍNÚ IGBÓ
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÍNÚ TÁN! LẸ́YÌN TÁWỌN AGBÉBỌN PA ÀWỌN ÈNÌYÀN NÍPAKÚPA, ÀWỌN Ọ̀DỌ́ YARÍ MỌ́ ÌJỌBA LỌ́WỌ́
OGUN WỌ̀LÚ O! ÀWỌN AGBÉBỌN YABO CHECKPOINT ÀWỌN CUSTOM, WỌ́N ṢEKÚ PA WỌ́N, NÁ BÁ KÓGUN WỌ̀LÚ