Orin 276 (E ba wa yo, ara ninu Kristi)
Автор: C.C.C. Ogudu Expressway Cathedral
Загружено: 2022-05-22
Просмотров: 29448
C.C.C Hymn 276 (Yoruba)
1. E ba wa yo, ara ninu
Kristi Fun o ri rere ta ni
Wakati buburu na de
Ti o mu aiye yi gbona
Elese ronupiwada
Ni ‘jo Mimo yi
2. Ogbun nla si sile nisisiyi
Lati t’eruku jade
Bo ko ba fe jeni egbe
Si odo Olugbala Re
Romo Kristi ‘nu Ijo Mimo yi
Yio ran o lowo
3. Laipe, Baba ki yio mo Omo
Tab’ ‘Omo mo Baba re,
K’aiye sile sa to Kristi
O duro loke Mimo Re
Rukerudo ‘parun nla mbo
Ya ronupiwada
4. Mo si tun nduro ninu anu mi
Npe awon elese
Wakati yi e paws da
Laipe anu yio dopin
Fi ‘ka, aje, orisa sile
Kristi yio, gba wa la
5. Gbogbo ekun aiye ti simi
Sibe nko bikita
Nko ro ewa ti Orun
Kika ni irun ori yin Lomu
Emi Kristi jiya na
Emi ni, wa, ki o ye
6. Niti iparun ti aiye yi
Mo fi anuu fa sehin
Sibe aigbagbo nposi
Nwon nsin orisa, aje
Nwon lo arakan ati ika
Fi won le wa ‘do mi
7. Mo ti pese ohun rere fun o
Ade didan iye na
Bugbe re nduro de o
Lori ile didara na
F’aiye sile, wa wa sodo mi
Emi o tewo gba o
Amin.
________________
Worship with us;
Wednesdays: Service for those seeking favor from the Lord - 9.00am.
Wednesdays: Mercy Day - 6:00pm.
Thursdays: Prophets Gathering - 10pm.
1st Thursday of each Month: New Moon Service - 10:00pm.
Fridays: Special Service for pregnant women - 3pm.
Fridays: Power Day - 6:00pm.
Sundays: Gory Service: 10a.m
________________
Address;
C.C.C. Ogudu Expressway Cathedral; 1/5, Celestial Way, Ogudu-Orioke, Ogudu, Lagos, 100242, Nigeria.
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: