GANI ADAMS KE GBAJARE SITA LORI IKOLU AWON AGBESUNMOMI, FOWOSI IRANLOWO OLOOGUN ILE AMERICA
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-11-20
Просмотров: 4132
GANI ADAMS KE GBAJARE SITA LORI IKOLU AWON AGBESUNMOMI, FOWOSI IRANLOWO OLOOGUN ILE AMERICA
Ìjọba ìpínlẹ̀ Kwara ti gbé àwọn ilẹkùn ilé ẹ̀kọ́ tì pa níjọba ìbílẹ̀ márùn-ún torí ètò ààbò tó mẹ́hẹ l'àgbègbè naa
Ààrẹ Tinubu bá mọlẹbí Ọgagun Uba táwọn agbébọn sekupa kẹ́dùn
O too gẹ o, Àwọn ọ̀dọ́ ìlú Eruku fẹ̀hónú hàn, nítorí iṣẹlẹ ìpànìyàn tó wáyé ní ṣọ́ọ̀ṣì CAC nípinlẹ Kwara
Inú ìbànújẹ́ ni èmi àti ìyàwó mi wà látìgbà tí wọ́n ti jí ọmọ wa lọ - Bàbá ọ̀kan lára àwọn akẹ́kọ̀ọ́bìnrin Kebbi lo kọminu bẹẹ
Ẹgbẹ òṣèlú ADC yóò f'opin sí iṣẹlẹ igbesunmọmi - Aregbesola lo sọrọ soke bẹẹ
Iba Gani Adams ke gbajare sita lori ikọlu awọn agbesunmọmi, fọwọsi iranlọwọ Ileesẹ olóògùn ilẹ Amẹrika
Olori oṣiṣẹ Ileesẹ olóògùn ilẹwa, Olufemi rọ awọn oṣiṣẹ olóògùn fẹyinti lati n'isẹ ọwọ kan ti wọn yóò ma se
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: