ILEEJO GIGA WOGILE ESUN IBANILORUKOJE TI IBA GANI ADAMS PE TAKO SUNDAY IGBOHO - DRIVETV YORUBA NEWS
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-07-05
Просмотров: 15987
ILEEJO GIGA WOGILE ESUN IBANILORUKOJE TI IBA GANI ADAMS PE TAKO SUNDAY IGBOHO - DRIVETV YORUBA NEWS
Iku d'oro o, Peter Rufai (Dodo-mayana), gbajúgbaja golí fún ìkọ Super Eagles, dagbere f'aye lẹni ọdun mọkanlelọgọta
Ileẹjọ gíga wọgile ẹsun ibanilórúkọjẹ́ ti Iba Gani Adams pe takò Sunday Igboho
O ma se o, awọn agbébọn ṣekúpa fijilanté mẹ́ta nípinlẹ Kwara, ìjọba gbé ọjà tìpa
Gbajumo Ọkunrin ori ayélujára TikTok, Tsulange ri ẹwọn ọdún kan he nipinlẹ Kano fẹsun pe o n wẹ nita-gbangba ninu awọtẹlẹ obinrin
Awọn obìnrin Benue gbegidina awọn oju ọna marosẹ nla, gúnlè iwọde takò Ifi-gbooro ofin gbe lọnà aibofinmu, bèèrè fún ìgbésẹ kanmọkobo lori ikọlu isekupani lemọlemọ to n t'ọwọ awọn Adaranjẹ waye
Ẹgbẹ oṣelu Labour Party fún Peter Obi ní gbèdéke láti fẹgbẹ́ sílẹ̀
#drivetv
#drivetvnews
#drivetv news yoruba
#drivetv yoruba
#drive tv yoruba
#drive tv news
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: