CCC HYMN 672: Gbo bi ipe na ti n dun l'orun
Автор: Celestial Hymnals
Загружено: 2025-11-15
Просмотров: 62
Gbo bi ipe na ti n dun l'orun,
Jesu duro ni bode orun,
Lati ko awon ayanfe Re,
Lo si ori ite Baba.
Mathew 24:31, Revelation 3:20
2. Awon angeli kun fayo,
Nwon nfun fere pelu ayo,
Baba ka mi mo awon eyi,
Ki nle ri Jesu lojo na.
3. Ore-ofe Re Baba la ntoro,
Agbara ati imisi Orun,
Ko wa ba wa gbe lojo oni,
K’alleluya le je orin wa.
2 Corinthians 13:14
#cccworldwideofficial #ccc #christianmusic
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: