IJOBA IPINLE OSUN TI FOFINDE AYEYE IKEKOOJADE FAWON AKEKOO ALAKOBERE IPELE NURSERY ATI JELE - OSINMI
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-09-20
Просмотров: 4671
Ọpẹ o, Adari agbebọn Garwa tu ogoji awọn Olufarakasa to wa nigbekun wọn sílẹ ni Katsina, o sekilọ fún ijọba Naíjíríà lori sisekọlu sí ibuba wọn
Ijọba ipinlẹ Ọsun ti fofinde ayẹyẹ ikẹkọ̀ọ́jade fawọn akẹkọ̀ọ́ alakọbẹrẹ ipele Nursery ati jẹle-osinmi
Ìdí ẹ re o ti ìjọba ipinlẹ Kwara fi gbé àgọ́ Àwọn àgùnbánirọ̀ kúrò níbi tó wà tẹlẹ lọ sínu Kwara Poly.
Ko s'ààrùn Ebọ́la lara wọn o, a ti ṣàyẹ̀wò f'awọn èèyàn méjì ti wọn ni wọn lùgbàdì ààrùn Ebọ́la ní Naijiria - Àjọ NCDC lo sọrọ jade bẹẹ takò iroyin to lugboro kan
Ọ́wọ́ tẹ o, ọwọ ọlọ́pàá tẹ agbálẹ̀ ilé ìwòsàn tí wọ́n bá ọ̀pọ̀ olubi ọmọ lọ́wọ́ rẹ̀ níbi tó ti fẹ́ tàá
Drivetv yoruba
drivetv news
drivetv news yoruba
yoruba new today
latest yoruba news
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: