Популярное

Музыка Кино и Анимация Автомобили Животные Спорт Путешествия Игры Юмор

Интересные видео

2025 Сериалы Трейлеры Новости Как сделать Видеоуроки Diy своими руками

Топ запросов

смотреть а4 schoolboy runaway турецкий сериал смотреть мультфильмы эдисон
dTub
Скачать

IBASE POLUWA KO TI WA NITIWA

Автор: Temitope Ogundolie

Загружено: 2019-05-12

Просмотров: 13605

Описание:

Oba mase pe Oluwa ti o ti wa ni tiwa” - Ps. 124:1 1.

lBASE p’Oluwa Ko ti wa ni tiwa
Lo ye k’awa ma wi
Nigbat’ese gbogun tiwa.

Egbe:
Ope ni f'Oluwa Oba wa Olore
A ke kabiyesi
A f'ope fun Jehofa
T'o gba wa Iowo ota, A dupe Oluwu.

2. Nwon ‘ba bo wa mole
Pelu agbara won,
Ope ni f ’Oluwa,
Ti ko jeki t’esu bori.

Egbe: Ope ni f'Oluwa...

3. Okan wa yo b'eiye
Nin' okun apeiye
Okun ja, awa yo,
E yo Jesu da wa sile.

Egbe: Ope ni f'Oluwa...

4. Tire ni Oluwa
Lati gbe wa leke
Gbogbo awon ota,
T'o wu ko tile yi wa ka.

Egbe: Ope ni f'Oluwa...

5. Ara f ’okan bale
Sodo Olugbala
B’esu ti gbon to ni,
Ko to kini kan fun Jesu.

Egbe: Ope ni f'Oluwa...

6. Iranlowo wa mbe
L'Oruko Oluwa
T’O d’orun on aiye
Oba awon eni Mimo.

Egbe: Ope ni f'Oluwa...

7. Ogo fun Baba wa,
Ogo fun Omo Re,
Ogo f’Emi Mimo
Metalokan jo gbo tiwa.

Egbe: Ope ni f'Oluwa Oba wa Olore A ke kabiyesi A f'ope fun Jehofa T'o gba wa Iowo ota, A dupe Oluwu. Amin

IBASE POLUWA KO TI WA NITIWA

Поделиться в:

Доступные форматы для скачивания:

Скачать видео mp4

  • Информация по загрузке:

Скачать аудио mp3

Похожие видео

ONISEGUN NLA WA NIHIN

ONISEGUN NLA WA NIHIN

Iba Se P'oluwa  - Hymn (Cover) - Wale Adebanjo

Iba Se P'oluwa - Hymn (Cover) - Wale Adebanjo

Джем – IBASE POLUWA KO TI WA NITIWA

Джем – IBASE POLUWA KO TI WA NITIWA

The Brooklyn Tabernacle Choir - Psalm 34 (Live Performance Video)

The Brooklyn Tabernacle Choir - Psalm 34 (Live Performance Video)

ПЕСНИ НА РОЖДЕСТВО / СЛУШАЙТЕ РОЖДЕСТВЕНСКИЕ ПЕСНИ

ПЕСНИ НА РОЖДЕСТВО / СЛУШАЙТЕ РОЖДЕСТВЕНСКИЕ ПЕСНИ

Ibase P' Oluwa

Ibase P' Oluwa

JESUS ONLY IS OUR MESSAGE

JESUS ONLY IS OUR MESSAGE

Ayo Ni O, Pt. 1

Ayo Ni O, Pt. 1

Ogo ni f'Oluwa to se ohun nla

Ogo ni f'Oluwa to se ohun nla

Ore Ofe Sha Ni Igbekele Mi/Yoruba Hymn/Video Hymn

Ore Ofe Sha Ni Igbekele Mi/Yoruba Hymn/Video Hymn

Bugbe Re Ti Lewa To

Bugbe Re Ti Lewa To

Jesus keep me near the cross by Fanny J Crosby & old rugged cross by George Bennard.

Jesus keep me near the cross by Fanny J Crosby & old rugged cross by George Bennard.

Moment of Worship  2.0 Temiloluwa Badmus ft Marysings

Moment of Worship 2.0 Temiloluwa Badmus ft Marysings

Arugbo Ojo - Segun Oluwayomi

Arugbo Ojo - Segun Oluwayomi

Ninu irin ajomi (AS I JOURNEY THROUGH THE LAND) | Adebunmi

Ninu irin ajomi (AS I JOURNEY THROUGH THE LAND) | Adebunmi

CeCe Winans: Goodness of God (Live)

CeCe Winans: Goodness of God (Live)

MZCE Choir - Onisegun Nla Wa Nihin

MZCE Choir - Onisegun Nla Wa Nihin

Oke Mimo, Pt. 4

Oke Mimo, Pt. 4

Otito Jesu f'agbara wenumo

Otito Jesu f'agbara wenumo

Рождественский альбом / Сборник христианских песен на Рождество #музыка  #рождественскаямузыка

Рождественский альбом / Сборник христианских песен на Рождество #музыка #рождественскаямузыка

© 2025 dtub. Все права защищены.

  • Контакты
  • О нас
  • Политика конфиденциальности

Контакты для правообладателей: [email protected]