AGBARA ORI ITE OYO ATIJO TI DITAN,KO SI OBA ILE YORUBA KANKAN TO LAGBARA JURAWON LO -ABESINKAWO AARE
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2026-01-20
Просмотров: 3556
AGBARA ORI ITE OYO ATIJO TI DITAN,KO SI OBA ILE YORUBA KANKAN TO LAGBARA JURAWON LO - ABESINKAWO AARE TINUBU LO SORO SOKE BEE
Agbara ori itẹ Ọyọ atijọ ti ditan, o ti kọja, Ko sí Ọba ilẹ Yorùbá kankan to lágbára jurawọn lọ - Abẹsinkawọ, Ààrẹ Tinubu lo sọrọ soke bẹẹ
Iku doro, Gbajumọ Olorin Afrofuji Destiny Boy dágbére f'aye lẹni ọdún mejilelogun
Ọyọ n pe mi, ki i ma sere, mo mà á dupò gómìnà Oyo ní 2027 – Oriyomi Hamzat lo soro soke bẹẹ
Iléẹjọ́ gba béèlí Portable pẹ̀lú mílíọ́nù kan náírà àti onídúró méjì, ohun tó ṣẹlẹ̀ ní ileẹjọ l'ọjọ Aje Mọnde rèé
Ìyá ló gbé bẹtiróòlù sí ṣọ́ọ̀bù ní Kwara tí iná fi jó ọmọ mẹ́ta pa-Iléeṣẹ panápaná lo salaye bẹẹ
Oniruru iṣoro lo n dojukọ Naijiria o, amọ sugbon teto aabo yi lobuaya to bori wọn.
Ọlọpa seesi yinbọn mọ awọn akinẹgbẹ rẹ meji nipinlẹ Rivers, èèyàn kan ku
Bírọ́ bá lọ f'ógún ọdún ọjọ́ kan lootọ o ba o, lẹyin ọdun mejila sẹyin Àjọ NDLEA nawọ mú Kanmo-Kanmo, afurasí olóògùn olóró tí wọ́n ló pa òṣìṣẹ́ àjọ náà mẹ́ta
Ohun ìtìjú lo je o'-Ìṣẹ̀lẹ̀ tó mú Senegal kúrò lórí pápá ìṣeré fún ìgbà díẹ̀ níbi ìdíje àṣekágbá Afcon 2025
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: