OHUNKÓHUN T’ÓLÚ BÁ TI YÀN
Автор: Concrete Studios
Загружено: 2025-03-01
Просмотров: 94
Composed by Late Rev (Dr)A.T. Ola Olude, PhD, KCW.
(Extract from Mayokun)
Ohunkóhun t’ Ólú bá ti yàn
Kìí ṣ’ ohun tió pa ni l’ára
Olórísun ire ni Òun
Ọlọ́run t’èmi, Ẹni tí
Dandan Re kìí tàsé,
Ó ńṣe kísa:
Ohunkóhun t’ Ólú mú fàle
Mo pé dandan, yíò gbehìn s’íre
Olórísun ire ni Òun
Ọlọ́run t’èmi, Ẹni tí
Dandan Re kìí tàsé,
Ó ńṣe kísa:
Ohunkóhun t’Ólú bá ti ko
Kìí ṣ ohun tí ó y’ o m’ Ọlọ́run
Olórísun ire ni Òun
Ọlọ́run t’èmi, Ẹni tí
Dandan Re kìí tàsé,
Ó ńṣe kísa:
Ohunkóhun t’ Ólú fún ni lò
L’à bá máa fi wá're Ẹgbẹ́ wa.
Olórísun ire ni Òun
Ọlọ́run t’èmi, Ẹni tí
Dandan Re kìí tàsé,
Ó ńṣe kísa:
Ohunkóhun t’ Ólu bá ṣe tì
Kìí ṣ ohun tí ó fa re mo ̣́ ni,
Egbe:- Olórísun ire ni Òun
Ọlọ́run t’èmi, Ẹni tí
Dandan Re kìí tàsé,
Ó ńṣe kísa:
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: