L’Owuro Ojo Ajinde / On The Resurrection Morning Yoruba
Автор: Hymns in Yoruba
Загружено: 2023-03-04
Просмотров: 6608
Easter Sunday Hymn written in 1864 and based on 1 Tesalonika 4: 16-17 "Nitori Oluwa tikararẹ̀ yio sọkalẹ lati ọrun wá ti on ti ariwo, pẹlu ohùn olori awọn angẹli, ati pẹlu ipè Ọlọrun; awọn okú ninu Kristi ni yio si kọ́ jinde:
Nigbana li a ó si gbà awa ti o wà lãye ti o si kù lẹhin soke pẹlu wọn sinu awọsanma, lati pade Oluwa li oju ọrun: bẹ̃li awa ó si ma wà titi lai lọdọ Oluwa."
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: