CCC HYMN 763 - OLUWA OLUGBALA JO GBA WA LA | YORUBA
Автор: CCC SHARON CHOIR
Загружено: 2024-08-04
Просмотров: 600
CCC HYMN 763 YORUBA
1. Oluwa Olugbala, jo gba wa la,
Awa eni mimo l’Orun mimo,
Awon angeli si nyo pelu wa,
Jo da wa lohun.
2. Bo tile pe Olugbala na yio wa.
La ti gba ‘wa elese la,
Dandan l’Oluwa nso fun wa,
Jo da wa lohun.
3. Wa dandan lati da wa l’ohun,
Awon to tan fitila mimo Re
Awon fitila mimo Re meje,
Jo da wa l'ohun.
Amin.
@cccSanctumParish
@cccakokaparish
@cccelephantandcastleparish
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: