HYMN 428
Автор: CCC Akoka Parish
Загружено: 2017-09-17
Просмотров: 17627
Hymn 428
Verse 1
Jehovah Onibu Ore
Ro 'jo Ibukun Mana Re
Sori awa ayanfe Re
L'arin wakati yi
Ibukun t'aiye ko le fi fun ni
Ire to so Okun
Di ona fun awon omo Isreal
Wa lana Ibukun rere fun wa
Wa se ti wa ni re.
Verse 2
Ire to pase fun awon
Eye Iwo lati wa fi
Akara at'eran didun
Bo woli Elijah
Leba odo Jordan
Jowo ranti
Awa ti nke pe O
Ki osi fi jije ati mimu
L'ona awamaridi bo wa ti Re
Oba Onibu ore.
Verse 3
Oba to gbekun Elizabeth
Awa omo Re nw'oju Re
Fomo rere se ranti wa
Oba Olupese
Jesu Oba Oluwosan Mimo
Wa wo awa tire san
Kawa le fi orin ayo sin O
Ninu Ijo Mimo Re lat'Orun wa
Olu f'ayo fun mi. (Amin)
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: