Isoro Ti Omo Araye Ko Naani // AKOKO IKORE
Автор: TREGO MEDIA
Загружено: 2022-01-07
Просмотров: 2845
AKOKO IKORE
Gbogbo ojo Eti, 6:45-7:00am
AKORI
Isoro Ti Omo Araye Ko Naani
Omo araye a ma saara lati yanju isoro owo, isoro ogun idile, isoro aso ati awon ohun ti aye yi. Sugbon eyi ti o gaju ti o ye ki omo araye o naani, won o ko biara si. Kini isoro naa?
#Yorubasermon #akokoikore #christianity #yoruba #nigerian
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: