AWON AGBEBON JI OBINRIN TO FE SE IGBEYAWO LAAARO OJO AJE MONDAY, ORE RE ATAWON MEJO MII GBE SALO
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-12-01
Просмотров: 1592
AWON AGBEBON JI OBINRIN TO FE SE IGBEYAWO LAAARO OJO AJE MONDAY, ORE RE ATAWON MEJO MII GBE SALO
Eemọ re o, awọn Agbébọn jí obìnrin tó fẹ́ ṣe ìgbéyàwó láàárọ̀ ọjọ Aje Mọnde, ọ̀rẹ́ rẹ̀ àtàwọn mẹ́jọ míì gbé salọ
O wa dojú ẹ bayi o, awọn agbebọn tun ji àgbẹ kan gbe salọ ni Eruku lẹyìn ọjọ diẹ ti wọn tu àwọn olùjọsìn mejidinlogoji silẹ
O tun sẹlẹ o, lorita Takie lOgbọmọsọ ọkọ flour Dangote sekupa ọlọkada atero to gbe lẹyin. Haaaa!
Erin wo, àjànàkú sùn bí òkè, Ọwa tí ìlú Igbajo l'Ọsun, Ọba Famodun wàjà lẹni ọdún metadinlaadọrun
Ileesẹ Ọlọpa bẹrẹ iṣẹ iwaadi lori Ọlọpa to sekọlu sí Agbero ọkọ bọọsi ti fídíò rẹ gba ori ayelujara kan l'Eko
Ọpẹ o, Ọba ti wọn jigbé salọ ní Kwara, ati awọn mẹfa mii ti moribọ́ kuro l'àhámọ́ awọn agbebọn
Ariwo sọ o, lori Orúkọ àwọn aṣojú Naijiria sílẹ̀ òkèèrè ti Tinubu fi ránṣẹ́ sí àwọn aṣòfin pe ki won o buwọlu
Tẹtẹ ni Bayo lọ tá to di gbese sí l'ọrun to fi da ọgbọn jiji ara rẹ gbe pamọ lati gb'owó l'Ògbómọ̀ṣọ́ - Pasitọ Ologunde lo tan imọlẹ sọrọ iṣẹlẹ ijinigbe to waye naa
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: