IJOBA IPINLE KWARA TI BERE SI NI F'OFIN GBE AWON ONIBARA NILU ILORIN - DRIVETV YORUBA NEWS
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-07-06
Просмотров: 17984
IJOBA IPINLE KWARA TI BERE SI NI F'OFIN GBE AWON ONIBARA NILU ILORIN - DRIVETV YORUBA NEWS
*Thomas Partey, agbabọ́ọ̀lù ìkọ Arsenal tẹlẹ di eero ileẹjọ nitori ẹsun ifipabanilopọ
*Ileẹjọ pàṣẹ ki ile aṣòfin pe Natasha Akpoti-Uduaghan pada sẹnu isẹ rẹ gẹgẹ bí aṣòfin
*Ijọba ipinlẹ Kwara ti bẹrẹ sí ni f'ofin gbe awọn onibárà nilu Ilorin olúìlú ipinlẹ Kwara
*Mo sa asalà fún ẹmi mi ni o, lẹyìn tí ìyàwó mi dunkoko lati da acidi sí mi lára - Ọkọ iyawo kan rọ ileẹjọ ko tu igbeyawo awọn ka
*O ma se o, baba ẹni ọdún marunlelaadọrin (75) d'àwátì l'Eko lẹyìn to tẹle mọlẹbi rẹ lọ ọgbà ileewosan
*O ma se o, Baba kan, ẹni aadọrin ọdún sekupa aburo rẹ tori ogún nipinlẹ Jigawa
*Akẹkọ̀ọ́ kan gún akẹkọ̀ọ́ akinẹgbẹ rẹ l'obinrin l'ọbẹ nigunkugun nipinlẹ Delta
#drivetv
#drivetvnews
#drivetv news yoruba
#drivetv yoruba
#drive tv yoruba
#drive tv news
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: