IJOBA APAPO GBERO LATI FI KWAME 1 SE AMBASSADOR, ASOJU AWON ESO ALAABO PAPAKO OFURUFU - YORUBA NEWS
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-08-13
Просмотров: 16224
IJOBA APAPO GBERO LATI FI KWAME 1 SE AMBASSADOR, ASOJU AWON ESO ALAABO PAPAKO OFURUFU - YORUBA NEWS
Ijọba apapọ gbero lati fi KWAM1 se Ambassador, Aṣoju awọn ẹṣọ alaabo papakọ ofurufu lẹyin iṣẹlẹ to waye nibi to ti ganu siwaju bàálù
Ìdí tí Tinubu fi gbọdọ̀ foríjin Kwam 1 gege bíi ọmọ onínàákúnàá re o MC Oluomo lo salaye ẹ bẹ.
Ijọba apapọ ti gbẹsẹkuro lori iwe ifisun iwa ọdaràn takò KWAM2 arìnrìnàjò Ibom Air, din ifofinde KWAM1 naa ku sí osu kan
Wọ́n tún ti n sálọ o, ẹlẹ́wọ̀n mẹ́rìndínlógún ló tún ti se bẹ ṣá kúrò lọ́gbà ẹ̀wọ̀n ní Nasarawa.
Ọwọ tẹ wọn o, Ileesẹ Ọlọpa nawọ gan awọn ọkunrin meji kan pẹlu agbari èèyàn mẹta nipinlẹ Ogun
Haa! Èèyàn márùn pade iku ojiji, awọn meji farapa ninu ìjàmbá ọkọ to waye loju ọna Lambata sí Suleja nipinlẹ Niger
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: