HYMN 621
Автор: CCC Akoka Parish
Загружено: 2017-09-24
Просмотров: 9150
HYMN 621
Maleka Mimo t'orun
Nwon ti t'orun sokale
Lati wa sure fun wa
Ninu Ijo Mimo
Enyin Omo Ijo Mimo
Mura Lati se ife re
Nitori O mbo Kankan
Lati be wa wo
Gbogbo 'enyin Oluponju
E korin ke ho f'ayo
Nitori Oluwa mbo
Yio da yin nide
Ayo wa yio ti po to
Nikehin ni ijoba orun
Bi awa ba le mura
S'ise Oluwa
Enyin Osise Oluwa
Mura lati sise na
Nitori ere nyin po
Li oke orun (Amin)
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: