WON TUN SOOSE LAABI WON O,AWON AGBEBON SEKUPA FIJILANTE MEEDOGUN LASIKKO TI WON SEKOLU SILU OKE-ODE
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-09-29
Просмотров: 8429
WON TUN SOOSE LAABI WON O,AWON AGBEBON SEKUPA FIJILANTE MEEDOGUN LASIKKO TI WON SEKOLU SILU OKE-ODE
Wọn tun ṣọọṣẹ laabi wọn o, awọn agbébọn ṣekupa fijilante mẹẹdogun lásìkò ti wọn sekọlù sílu Oke-Ọdẹ nipinlẹ Kwara
Awọn èèyàn bù ẹnu àtẹ lù Peter Obi lori bo se pe Olúbàdàn l'arakunrin rẹ, Obi sọ idi to fi pe bẹẹ
Àṣà àti ìṣe ló sọnù tí ìjà àgbà fi ń wáyé láàárín àwọn Ọba Yorùbá
A o fẹ bororo, a o fẹ fulani bẹẹ la o fẹ Meyẹti Allah lawọn ilu wa mọ o, fun idi eyi a rọ ijọba, ẹ bawa ti awọn ọja Kara pa ni gbogbo ilu ti o wa nijọba ibilẹ guusu Kwara.
Ìjọba àpapọ̀ sanwó àwọn Káńsù sí àpò àwọn alága ẹgbẹ́ APC l'Ọsun, lọ̀rọ̀ badi gbasgbos, ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ àti ìjọba Ọsun bá fárígá
He-heee Ajínigbé jí lọ́yà tí wọn ṣẹ̀ṣẹ̀ búra fún pẹ̀lú ìbátan rẹ̀, l'ẹgbẹ́ awọn agbẹjọ́rò ba ń rawọ́ ẹ̀bẹ̀ pe ki wọn dakun dabọ tu silẹ.
Ẹ wá gbọ́ o Àdínkù yoo bá owó Hajj, iye tí àwọn Alálàájì yóò san lọ sí Mecca lọdun 2026
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: