NKAN DE O! AWON AGBEBON JI IGBAKEJI OLORI ILE IGBIMO ASOFIN IPINLE KEBBI GBE LO -DRIVETV YORUBA NEWS
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-11-02
Просмотров: 8054
NKAN DE O! AWON AGBEBON JI IGBAKEJI OLORI ILE IGBIMO ASOFIN IPINLE KEBBI GBE LO -DRIVETV YORUBA NEWS
Ẹni ba sekupayan, iku lere ẹsẹ rẹ, Baba mi sekupa iya mi, Mo faramọ ti wọn ba ṣekupa baba mi
Isẹ́ti yá o, mo ti dé padà, Peju Ogunmola kéde pé òun bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà padà lẹ́yìn oṣù méjì tí ọmọ rẹ̀ kú
Nkan de o, Àwọn agbébọn jí Igbákejì olórí ilé ìgbìmọ̀ aṣofin ipinle Kebbi gbé lọ
Ẹ gbọ́ naa, Àkóbá wo ló le se bí Ààrẹ Trump ṣe kéde Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bíi orílẹ̀ èdè tí ọ̀pọ̀ Krìstẹ́nì ti ń pàdánù ẹ̀mí ju.
Ileese Olopa nawo gan adigunjale kan, awon meta na papa bora nipinle Kebbi
Bi nkan se nlọ yi, o ma seese ki owo epo bẹntiro tun lo soke si, pẹlu bi Aarẹ Tinubu se buwọ́lu àfikún 15% owó orí epo bẹntiroolu àti disu.
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: