IJOBA IPINLE EKO SO OKODORO NNKAN TO SELE LORI ITUSILE BABA IJESA LOGBA EWON YATO SI ORO TO GBALE
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-11-17
Просмотров: 7492
IJOBA IPINLE EKO SO OKODORO NNKAN TO SELE LORI ITUSILE BABA IJESA LOGBA EWON YATO SI AHESO ORO TO GBALE
Irọ́ ni o, irọ ni ìròyìn pé àwọn kan fẹ́ sekọlu lati fẹ gbẹ̀mí Yerima nílùú Abuja agbẹnusọ ileeṣẹ ọlọpaa Abuja lo sọ bẹ
B'ọrọ itusilẹ Baba Ijẹsha se jẹ re o, Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko sọ òkodoro nǹkan tó ṣẹlẹ̀ lórí ìtúsílẹ̀ Baba Ijesa lọ́gbà ẹ̀wọ̀n yàtọ̀ sí àhesọ ọ̀rọ̀ tó gbalẹ̀
Ẹgbọ naa Tani Kabiru Tanimu Turaki tí wọ́n yàn bíi alága ẹgbẹ́ òṣèlú PDP awọn eeyan fe mọ.
Mo ṣetán láti jápa o, tí orílẹ́èdè ilẹ̀ òkèèrè kan bá fún mi ní 'asylum' - Hauwa Lawal gbajúgbajà sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ orí ayelujara lo sọ bẹ
Awọn onimọ nipa eto aabo sàlàyé nipa ohun tó ń fa ìjà láàárín àwọn alakatakiti ẹsin Boko Haram àti ISWAP
Kàyéfì, wọn ba oku ọmọ Nàìjíria to n gbe nilẹ Amẹrika ninu ọkọ akẹru
Òsèlú bẹ̀rẹ̀ o, Igbimọ lẹgbẹ oselu PDP fọwọ́ òsì júwe ilé fún Wike, Fayose àti àwọn mẹ́wàá míì lẹgbẹ òsèlú naa.
Kó sọwọ mi níbi mọ daru o, bẹẹni nko lọwọ si ìyọnípó Wike lẹ́gbẹ́ oselu PDP, Gómìnà Fintiri lo ṣalaye ọrọ bẹẹ.
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: