ORO DOJU E AWON OMOOBA YO AWON AFOBAJE LOYE NI IPETUMODU LEYIN TI WON KO LATI YO OBA APETUMODU
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-09-11
Просмотров: 10374
Ọrọ dojú ẹ, àwọn ọmọọba yọ àwọn afọbajẹ lóyè ní Ipetumodu lẹyìn ti wọn kọ lati yọ Ọba Apetumodu ti ijọba ilẹ Amẹrika ran lọ s'ẹwọn kuro lori itẹ
Ìdí rèé o tí iléẹjọ́ ṣe kọ láti gba béèlì afurasí márùn-ún tó sekọlu si ṣọ́ọ̀ṣì Owo nibi ti ogójì èèyàn ti pade iku ojiji
Iná agbára mọ̀nàmọ́ná tun ku pii jakejado Nàìjíríà, sọ awọn èèyàn sínú okunkun l'Ọjọru Wednesday
ko jọ rara - Ọba alayé kan nílẹ̀ Yorùbá fariga, ó pe ẹni to f'ara rẹ jẹ 'Obi of Lagos' lẹ́jọ́
Ìyá mi ti kú, òṣìṣẹ́fẹ̀yìntì ni bàbá mi, mò ń fi ìwé ẹ̀rí NCE ta Puff-puff, kí gómìnà Adeleke tó gbà mí síṣẹ́ - Oluwatomisin Adejumo lo sọrọ jade bẹẹ*
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: