E SORA O,OTI SORO LATI MU NI NAIJIRIA ATAWON ORILEEDE KAN BAYII O KEMIKA METHANOL NI WON N PO PO
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-10-24
Просмотров: 8097
E SORA O,OTI SORO LATI MU NI NAIJIRIA ATAWON ORILEEDE KAN BAYII O KEMIKA METHANOL NI WON N PO PO
Ààrẹ Tinubu yan ọgagun Oluyede gẹgẹ bí olori oṣiṣẹ ọmọ ogùn ilẹwa Naijiria tuntun lati rọpo Ọgagun Musa, bi ààrẹ tun se yọ awọn olori oṣiṣẹ mii naa kuro nipo
Ifura logun agba, Ẹ ṣọ́ra o, ọtí ṣòro láti mu ní Nàìjíríà àtàwọn orílẹ̀èdè kan báyìí o,kẹ́míkà methanol ní wọ́n ń pò pọ̀ - ijọba ilẹ gẹẹsi UK lo ṣèkìlọ̀ bẹẹ f'awọn aráàlú
Tuntun ti de o, Banki apapọ ilẹwa CBN ti gbé òfin tuntun àtàwọn ìlànà míràn tó kàn ọ́ kalẹ̀ nípa àìrówó gbà oníbaarà lẹ́yìn to ba lo ẹ̀rọ ipọwójade ATM
Ìròyìn ofege ni ìròyìn tó sọ pe ìjọba Seyi Makinde fẹ bẹ́rẹ́ owó orí gbígbá lórí ayẹyẹ ìsìnkú, ìsọmọlórúkọ, ìgbéyàwó àtàwọn ayẹyẹ míràn nipinlẹ Ọyọ
Emi funra mi mo maa ṣe agbẹjọro ara mi" - Nnamdi Kanu, da àwọn agbẹjọ́rò rẹ̀ nu lẹ́yìn tó dárúkọ Sanwo-Olu, Malami àtàwọn míì gẹ́gẹ́bí ẹlẹ́rìí rẹ̀ nílé ẹjọ́
Gómìnà ìpínlẹ̀ Niger gbe milliọnu kan náírà N1m kalẹ fún ọkọọkan ìdílé àwọn Olufarakasa to forilugbadi iṣẹlẹ ìjàmbá ọkọ tanka epo to gbana jẹ
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео mp4
-
Информация по загрузке: